Home / Àṣà Oòduà / Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí egbé yàn láti lo fún Gómìnà ìpínlè won ní Osun, Seneto Ademola Adeleke tí ìlú ede ní ìpínlè Osun.

About Awo

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?