Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà ...
Read More »Ejìnrìn Wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀
Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági lọ́run ...
Read More »Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó ...
Read More »Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò ...
Read More »Yorùbá dún
Hà à à!! Elédùmàrè ìgbà wo l’ènìyàn yόò to bo nínú hílàhílo òde ayé yìí nà? Ki baálé ilé jáde láti òwúrò kùtùkùtù àná kό sí ma b’ojú wéhìn wo, Ǹjé irú ìwà béè daa?? Àmò sà à!! Èyí tà ...
Read More »È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé ...
Read More »Àwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).
Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí ...
Read More »Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà ...
Read More »Òrò ìsítí gbó òréëwa?
Òrò ìsítí gbó òréëwa? -O féékú wàákú, Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, ...
Read More »E ku Ose Sango
Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun…Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun gbogbo Otawa aori tiwase.E ku ose sango, Ase ...
Read More »