Home / Àṣà Oòduà / E ku Ose Sango

E ku Ose Sango

Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun…Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun gbogbo Otawa aori tiwase.E ku ose sango,
Ase Edumare..
AWO OSA LOGBE.

About ayangalu

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo