Home / Àṣà Oòduà / Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko.
Bákan náà, won tún sí ojú olú polówó ojà won tí a mò sí Cee-C.

 

About Awo

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?