Home / Tag Archives: Eko

Tag Archives: Eko

Fidio: Ipinle Eko

Read More »

Sanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan ...

Read More »

Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn

Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn – Ìròyìn lati o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo buruku esu gbomi mu ni ojo isinmi oni je fun awon ara agbegbe Amuwo Odofin ni adugbo FESTAC.Ijamba ina naa bere ni aago mesan-an aaro. Opa epo ni ...

Read More »

Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ Chrisland

Sanwo-olu dáhùn ìbéèrè okada ló̩wó̩ aké̩kò̩ó̩ ChrislandLáti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíGomina Babajide Sanwo-olu ti ipinle Eko lo n dahun orisiirisii ibeere lowo awon akekoo ile-iwe Chrisland to wa ni ilu Opebi ni Eko, nigba ti o gba won lalejo ni oni ...

Read More »