Home / Tag Archives: Iwure (page 2)

Tag Archives: Iwure

Iwure Owuro 21/03/2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...

Read More »

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...

Read More »