Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.

Gégé bí ò n lò èro ayélujára (Facebook)se so, odókùnrin yí ye kí ó se ìgbéyàwó ni osù kejìlá sùgbón ó ti di olóògbé. Ó kú nínú ìjàmbá pèlú àwon tí ó kùn rè.
Kí olórun te sí aféfé rere.
Kí á sì má rí irú rè mo.

Comments

One response to “Ó ye kí ó se ìgbéyàwó ní ojó kejì osù kejìlá odún yí (2nd of December) sùgbón ó ti di olóògbé.”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *