Gégé bí Sani tí ó pin se so, àwon èèyàn Bachama ní alé àná ti dojú ìjà ko àwon fúlàní ní ilé tí won ngbé ní Kwadam Shafaran ìlú kéréje kan ní Numan ti ìpínlè Adamawa. Ó kéré jù márùnlélógójì (45) ni àwon fúlàní tí won pa tí òpò sì fi ara pa .
Òkú àwon tí ó kú ti wà ní Mósúárì tí ó wà ní Numan tí àwon tí ó fi ara pa sì wà ní ilé-ìwòsàn.
Home / Àṣà Oòduà / Àwon ará ìlú dojú ìjà ko àwon Fúlàní ní Numan, Adamawa wón pa  márùnlélógójì(45) tí won sì fi ogbé sì àwon tí ô kù l’ára .
		
		
		
		Tagged with: Àṣà Yorùbá
 Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
				
