Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .

Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .

Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó .
Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé kí ó wo nkan tí yóò tún ma kó oeó lé lórí dáadáa nínú àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won tí won ya.
Èyí rewà ó pò jù.

About Awo

x

Check Also

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà.

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú Cameroon ní méta sí Méjì, (3-2), ní gbàgede pápá ti Alexandria láti le wo ìpele kèta sí ife. Jude Odion Ighalo ló gbá méjì wo ilé àwon alátakò won, tí Alex Iwobi sì gbá ìkan tí ó kùn wolé. Nse ni ó dàbí ...