Home / Àṣà Oòduà / Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.
Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò.
Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí kò wá máa se èyà tirè lóótò? Tí kò le d ilé isè tirè náà sílè.

About Awo

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?