Home / Àṣà Oòduà / Ìyá omo Davido, Amanda, ti se ayeye ojó ìbí fún Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún (25).

Ìyá omo Davido, Amanda, ti se ayeye ojó ìbí fún Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún (25).

     Amanda, tí ó n gbé ní Atlanta tí ó jé ìyá omo olórin orílè èdè Nàíjíríà, Davido, pin sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-story)láti se ayeye ojó ìbí Davido nígbà tí ó pé odún márùnlélógún.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?