Omokùnrin Ronke Oshodi Oke, Richmond se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè.

Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke.
Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè, ará òré ti péjú sí ìbí ayeye náà.

Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *