Home / Àṣà Oòduà / Tracy àti Treasure Daniel se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tí ó ya ni lénu.

Tracy àti Treasure Daniel se ayeye ojó ìbí won pèlú àwòrán tí ó ya ni lénu.

    Àwon òsèré tí ewà won ya ni lénu tí ó sì pa ni kú ni àwon ìbejì yí . Treasure àti Tracy Daniel tún lé odún kan si . Àwon ìbejì yí ti hàn ní àìmoye eré orí ìtàgé tí ó ti ju igba (200) ní orílè èdè yí àti míràn, àwon ni won sábà máa n lò jù fún ìbejì nínú erè…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...