Home / Àṣà Oòduà / Asòfin egbé APC, tí a mò sí Hon. Timothy Owoeye, fi èjè wè ní òrú gànjó.

Asòfin egbé APC, tí a mò sí Hon. Timothy Owoeye, fi èjè wè ní òrú gànjó.

Owó pálábá Asòfin egbé APC tí ó sì jé gbòógì , tí ó sì jé asojú ilé ìgbìmò asòfin tí Ilésà ní ìpínlè Osun, ni owó bá nígbà tí ó n fi èjè wè ní àrin òru tí ó sì n be àwon ará agbègbè náà kí won má se bínú.

Tí ó bá ti è jé wípé ibò míràn ni ó ti wè é ni ò se é se kí owó pálábá rè má ségi súgbón òkété rè kò bímo etílé àrin ojà ni ó ti n fi wè.
Èyin ìjoba wa èbè la bèyín kí e má se jé kí òsèlú gba omolúàbí.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo