Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.
Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò.
Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde Dasilva náà wo èyìn wò nígbà tí ó pín àwòrán ìgbà èwe rè sì orí èro ayélujára insítágírámú.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo