Home / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti

Gbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti

Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ní Baby J.

Ó ko síbè wípé…
Òlúwa, èmi náà ti di ìyà, Baby J ti dé! Mo bímo ní ojó ketàdínlógún, eléyìí wuyì púpò. Modúpé púpò èyin èèyàn mi fún àtìleyìn yín fún ìrìnàjo náà. Mo ní’ìfé yín.

About Awo

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?