Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó selè ní òpópónà Ibadan sí Èkó.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó selè ní òpópónà Ibadan sí Èkó.

Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè.
Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé ìjambá náa selè tí ó dì kò kalè láti ràn wón lówó. Ìjàmbá okò yí selè ní òpin Ibadan ní ìyànà Sagamu.
Ní òpópónà Ibadan sí Ekoní ìpínlè Ògún ní agogo méjìlà àbò òsán.
Oyetola nígbà tí ó débè ó jáde kúrò nínú okò rè láti ran awon tí ìsèlè yí selè sí lówó.
Oyetola tún gbìyànjú báwon pe ilé-ìwòsàn ní kíákíá.
Ìjàmba yí selè láàrin oko Toyota Corolla fúdú ati okò elérò méjìlá. Won ni oko elérò yí ti tàkìtì láìmoye ìgbà nígba tí ó tí so owó okò nù.
Bí ó tilè je wípé bí ó se selè pò ju báyìí lo súgbón èyí tí a rígbó nìyí.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo