Àkòrò ní ìgbín fà gungi
Ìgbín kò lọ́wọ́
Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀
Àkòrò ní ìgbín fà gungi
Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní já sófo
Pages: 1 2
Ààrẹ Tinubu ti yan Alhaja Ero Arike sí ẹgbẹ́ Ìgbìmọ̀ Àwọn Oníròyìn Tuntun(New Media Committee) tó máa kópa nínú ìpolongo rẹ̀ fún ìdìbò Ààrẹ ọdún 2027. Ká ma purọ́, Obìnrin náà ń gbìyànjúTó bá jẹ́ pé ẹni tó bá gbé APC sí orí bíi gala wọ́n ń wá, Alhaja Ero Arike náà ti gbé e sí orí, kó sì fẹ́ràn láti sọ̀kalẹ̀ rárá Ó ti ń ṣe ohun tí ó lè ṣe láti gbé ìjọba àti ẹgbẹ́ APC lárugẹ lórí ...