Home / Àṣà Oòduà / Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Olódùmarè mà tóbi lóba ooo.

Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún.
Òdú ìfá ni ó sì n se atóka ohun gbogbo, odù ifá náà bèrè láti orí Èjìogbè dé Òfún méjì.
Olódùmarè ti se atóka rè sí orílè alàyè a sì rí odù Ejìogbè ní ara Eranko Ewúró.
Njé Olódùmarè yí kò tóbi bí.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo