Home / Author Archives: oodua (page 3)

Author Archives: oodua

Olojo Ibi

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...

Read More »

Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?

Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?  

Read More »

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...

Read More »

Ojuitere ooooooo!!

mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni ...

Read More »

Eyin tia, e ku isinmi oni!

ARAYE KONI LU FUN WA JO, BATA-OFO, BATA- IBANUJE BATA-WAHALA won o ni bo si enu- onan gbogbo wa, gbogbo eniyan tiko ba yan Eledua l’odi e bami se ase, toripe INU- ALAGBAFO KI LE TITI KO BINU OMI. oju-itere ...

Read More »

Ngozi Nwosu lori eto Gbajumo Osere

Read More »

What Ifa Says in Ogbe Ate

In Ogbe Ate, Ifa says everybody should do Itefa (Ifa initiation) to know one’s mission on earth, one’s destiny and in order to have all good things of life. A ki i ji ni kutukutu/ Ka ma modu to dani ...

Read More »

Edurona ibo la nba oro epo lo ni 9ja bai ooooo … ?

Elo leyin nra epo ladugbo yin????

Read More »

Ojopagogo lori eto Gbajumo Osere

Read More »

‪#‎Gbagede Asa-19/03/2016

Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa. ……. Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni ...

Read More »