Gégé bí olùrànlówó oníròyìn ti ìjoba ìpínlè Sokoto, Imam Imam òsìsé ológun (army officer) M Maiwada àwòrán eni tí ó wà lókè tí ó sèsè di Balogun (captain) ni won yín ìbon pa ní ojú ogun pèlú àwon Boko Haram ...
Read More »John Nani Pa Olúfà Ńlá, John Nani Tí Ó Jé Konmísónà Ní Ìpínlè Delta.
Konmísónà tí ó ń mójú tó àyíká (commissioner of environment), tí a mò sí Hon. Barr John Nani àti àwon emèwà rè kolu tí won sì pa olúfà ńlá tí ó won òsùwòn tí ó tó mítà lónà mérin ó ...
Read More »Akékòó ilé -èkó Nwafor Orizu College Nsugbe ni àwon omo egbé òkùnkùn yin ìbon pa.
Léyìn àrídájú tó ji-n-gí-ri, mo le f’owó s’òyà pé pé ilé-èkó Nwafor Orizu College of Education Nsugbe ti pàdánù tí ó pò . Arákùnrin Mr Osaji Charles, tí ó jé Mr NASELS télè (2013/2014 session), ni won yín ...
Read More »Èsì ìdánwò alásekágbá ilé-èkó girama (waec)tí ó burúkú jù nínú odún 2017, tí a rí he.
Láàrin ogún-l’ógbòn àwon akékòó tí ó tó 1,559,162 tí won jòkó fún ìdánwò àsekágbá ilé -èkó girama tí a mò sí waec ní odún 2017 tí ó jé wípé òpò ni a ti rí, tí ó sì dára … Akékòó ...
Read More »Ìbon ba àwon ajínigbé nígbà tí won ń dúnà pàsípààrò lówó ní ìjoba ìpínlè Abia.
Àwon ajínigbé mérin, èyí tí won ti ń da ìpínlè Abia àti agbègbè rè láàmú. Won ti ń gbìyànjú àti parun tí àwon òtelèmúyé so mó Omoba Division ní ojó ketàdínlógún osù keje (19th July ,2017) ní Ovungwu, Isiala -Ngwa ...
Read More »Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An Introverted Wife)
Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà ...
Read More »Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje àjòdún Washington DC jollof.
Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway Restaurant &catering in Maryland US, ti se ipò ...
Read More »Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task force) nígbà tí owó bà wón ní Benue.
Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ...
Read More »Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)
E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ
A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »