Home / Àṣà Oòduà / Eledumare iba re loni o…

Eledumare iba re loni o…

Eledumare iba re loni o,akoda aiye iba,aseda aiye iba,baba mi odetunde iba re loni o,iya mi iba re,iba oluwo ,iba iya nifa,iba olojo oni, aku ose ogun o,ogun yio bawa se o,ao ni tele lodi,ogun yio la ona fun wa o,Happy today’s ogun spiritual week. Ogun yee mo yee,iru ni aja fi n yin olowo re.
eledumare

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...