Home / Iroyin Pajawiri (page 117)

Iroyin Pajawiri

“Gbajue paraku ni Dokita Akintunde Ayeni” -Onibara Yem-Kem lo so bee

Arabirin Bamidele Ademola-Olateju lo gbe atejade kan sori ero FACEBOOK re nipa alase Yem-Kem International, Dokita Akintunde Ayeni. O ni gbajue paraku ni  maanu naa. Ohun ti arabirin Bamidele tun wa fi kun un ni wi pe,  Dokita Akintunde ti ...

Read More »

Fayose niso eleja

E tun gbe yewo, Gomina Foyose tun gbe sunmo iya eleja.

Read More »

Oba’binrin Asa Solaade Iyaasa: Ohun IFA ati Iwure

ÒÒṢÀ ÒKÈ, ÌBÀ IFA ni ti a ba ji a ki OLU OLU moji mo ki o loni IFA ni to a ba ji a ki Osin, osin moji mo ki o loni ELA ni kan ni somo bibi inu ...

Read More »

Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo

Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo ...

Read More »

Awon Foto Kunle Afolayan niluu Kenya

Die ni yii ninu ibudo ere fiimu tuntun Kunle Afolayan, The CEO, ni ilu Nairobi to wa ni Kenya.

Read More »

E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko

Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju ...

Read More »

Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe

Ojo gbobo ni tole, ojo kan pere ni tolohun. Owo palanba awon igara olosa kan segi laaro ana ni agbegbe Olowotedo Mowe to wa ni masose Eko si Ibadan. Ikanra ni awon eniyan agbegbe naa fi na awon ole taa ...

Read More »

Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India

Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. ...

Read More »

Eto idibo gomina ipinle Kogi di fopomoyo

*Faleke n binu, ara ilu n sofo *Iwe ofin ruju mo awon amofin loju *Won tun ni kan fomo Audu je gomina apapandodo Leyin iku Abubakar Audu, oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Kogi, eni to jade ...

Read More »

Atelewo eni ki i tanni i je

Awon Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pese ohun ti awon omo won ba n fe nikan, bikose lati sakiyesi iru ebun ti ...

Read More »