NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Ajeji Gisiti Atunyẹwo Awọn Iroyin Agbegbe Ẹṣọ Aṣọ Iroyin Pajawiri

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

  • May 8, 2025
  • 1 min read
  • 11 Views
[addtoany]
Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn

Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀.

O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han.

Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika.

Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, nigba ti ọta ibọn kan lojiji gba oju ferese wole.

“Mo ti ka a ni ibi kan wi pe awọn wọnyi je ọlaju eniyan. Sọ fun mi pe o wa ni Amẹ́ríkà lai so fun mi pe o wa ni Amẹ́ríkà. Mo n sere ninu yara igbalejo mi kan ati lojiji ariwo yi sele “, gege bi o se salaye.

About Author

asatiwa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *