Home / Metro life (page 3)

Metro life

Gobe Sele Nigba Ti Omo Yari Wi Pe Oun o ni fohin

Yorùbá Dùn shared the following link and had this to say about it: Oloorun ni omo naa, ko fe ki won ba fohin re lero ni won ba mu lele fun un. Nje ohun to buru wa ninu igbese ti ...

Read More »

Iroyin Pajawiri: Olori egbe awon asewo Naijiria, Jessica Elvis ti ku

Iroyin yajo-yajo to sare wole yii lo n salaye wi pe arabirin Jessica Elvis to je olori egbe awon asewo, oninabi ile Naijiria ti rekoja lo sorun.

Read More »

Nje ohun to buru wa ninu ara bibo?

Nje ohun to buru wa ninu ara bibo? Idahun awon eniyan wa ninu linki isale yii: https://www.facebook.com/photo.php?fbid=904657846286766&set=gm.1070531176331524&type=3

Read More »

E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re

Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan ...

Read More »

E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba

Laaarin ile itaja nla kan niluu Warri, bobo yii kunle fun ololufe re. O mu oruka ife jade lapo, o si wi bayii wi pe: “Joo ololufe mi, nje o gba lati je iyawo mi?” Opolopo awon eniyan ti won ...

Read More »

Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. ...

Read More »

Grandson Blows Hot Again! Hotter Actually!!

Lets hear your thoughts in the comment box bellow.

Read More »

Photos of Alaafin of Oyo spotted with his Oloris

The royal highness was spotted with his beautiful Oloris going to the mosque for Friday prayers.

Read More »