Home / Aarin Buzi (page 5)

Aarin Buzi

Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara

O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...

Read More »

Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro

Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni

Read More »

“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo

Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...

Read More »

Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa

Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge.  Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.

Read More »

London, e ku amojuba Omo Baba Olowo

Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London. Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?

Read More »

Akoni osere onitiata: Bimbo Thomas gbayi!

Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata ...

Read More »

Ohun ti Laide Bakare gbe soke ko daa rara

Laide Bakare ti pada si lo n se esesaisi lati pada ri bi omidan, se e mo wi pe awon obirin kii fe darugbo kiakian, ka to wa so wi pe osere. Bakan naa ni awon onise tiata kii fe ...

Read More »

Awon wo ni Kunle Afolayan sepe fun?

Ogbontarigi onise tiata, Kunle Afolayan ti fepe ranse fun awon ti kii ra ojulowo fiimu ti won se sita, to je wi pe ayederu ti awon onisedudu n se ni won ra. “To o ba ra ayederu sinima mi tabi ...

Read More »

Omidan to n wa ore tuntun fi leta ati Foto re ranse

Omidan Toyin lo kowe si wa wi pe oun fe ore, ko so wi pe oun wa oko o. Awon ore tuntun lo n fe, eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Awon to ba nife sii le fi ...

Read More »

Igo dudu meta: Toyin Aimakhu, Muyiwa Ademola ati Eniola Badmus

E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?

Read More »