Home / Aarin Buzi / Omidan to n wa ore tuntun fi leta ati Foto re ranse

Omidan to n wa ore tuntun fi leta ati Foto re ranse

Omidan Toyin lo kowe si wa wi pe oun fe ore, ko so wi pe oun wa oko o. Awon ore tuntun lo n fe, eni ti won yoo jo maa takuroso lasan.
Awon to ba nife sii le fi number tabi bb pin won sile nigba ti Toyin yoo ma kan si awon to fe lati ba won dorepo. Yoo dara ki e se alaye die nipa ara yin pelu. E se.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?