Home / Aarin Buzi (page 6)

Aarin Buzi

Foto: Davido se baba gidi fomo re

Sebi tori omo naa la se n sise… Omoomo baba olowo

Read More »

Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife

Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola.

Read More »

Mama o fe e gba: Iyabo Ojo ati omo re

Edumare ma pa omo folomo. Ti eniyan ba ri omo Iyabo Ojo, eniyan le sebi boya aburo re ni. Iya gan-an ni ko si fe gba yii. Oga ju!

Read More »

Won ti gbe oye Dokita fun Oba Lamidi Adeyemi III

Leyin ayeye ojo ibi odun metadinlogorin (77) Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi III to waye laipe yii, awon ojongbon tun ti pawopo fi oye Dokita da Alaafin Oyo lola. Ayeye yii lo waye l’Ojoru to koja yii nibi won ti ...

Read More »

Se Ruggedman ba iyawo 9ice sun looto?

Se Ruggedman ba iyawo 9ice sun looto? *Adigun Alapomeji ti pada soro *Asiri ikoko ti de gbangba Olayemi Olatilewa 9ice ati Toni Alexander Abolore Ajifolajifaola eni ti gbogbo eniyan mo si 9ice ti ni oun ko ni darijin ore oun ...

Read More »

E wo ohun ti Funke Akindele n se lowo?

Funke Akindele ti pada si ni sere idaraya eleyii to n se lati din ara sisan re ku. Awon obirin onise tiata maa n se eleyii lati mu ara awon wa ni ipo odo, eleyii to se pataki si irufe ...

Read More »

Igba wo ni Pasuma fe ni Aya leyin odun mokandilaadota (49)?

Igba wo ni Pasuma fe n’iyawo leyin odun mokandilaadota (49)? Olayemi Olatilewa Wasiu Alabi Pasuma tun ti pada so fun awon ololufe re wi pe ko ti to asiko fun oun lati ni iyawo nile. Oga Nla fuji, eni ti ...

Read More »

Ori iya mi ooooo! Ukwu ore Yemi Alade ti da gobe sile o.

Wahala ti bere si ni sele lori ayelukara bayii, eleyii si bere nikete ti Yemi Alade se afihan foto re pelu awon ore, eni to se apejuwe won gege awon ololufe orin re. Awon eniyan ko tile soro nipa Yemi ...

Read More »