Won ti yan Ooni tuntun ni Ile-Ife Posted by: oodua in Aarin Buzi, Àṣà Oòduà 0 Awon afobaje ilu Ile-Ife ti yan Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi lati idile Giesi gege bi Ooni tuntun bayii. Won si ti fi oruko oba tuntun naa ranse si gomina ipinle Osun, ogbeni Rauf Aregbesola. ooni 2015-10-26 oodua tweet