Home / Àṣà Oòduà / Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..

Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..

Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù,
Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí.
Àlékún owó,
Àlékún ogbón,
Àlékún ìmò,
Àlékún ìgbéga
Àlékún ohunrere gbogbo ni yóò máa jé tiyín láse Èdùmàrè. Ìgba odún, odún kan ni o.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo