Home / Àṣà Oòduà / Ayo Ab’ara Bintin

Ayo Ab’ara Bintin

Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun wa wipe Eledua fi Omobinrin lantalanta da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Olori AJOKE GOLD OLUWAKEMI ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata.

A wa ngba ni adura wipe, a ti mo ibere omo yi, a o ni mo opin re lase Edumare. Aisan ti n se iya omo leyin ibi omo ko ya nile lodo yin ni oruko Oluwa. Gbogbo ohun ti e nilo lati fi to omo yi ti yoo fi je eniyan laye ni Eledua yoo fi s’eke yin.

Ki Olodumare wa wo ola omo tuntun jojolo yi, gbogbo eda ti nwoju Oluwa fun ohun ayo bayi ki oba mi oke wa dawon lohun ni kia lase Edumare.

OLORI AJOKE GOLD GBOGBO EBI OMO YORUBA ATATA NILE-LOKO ATI LEYIN ODI NKI YIN WIPE, E SI KU OWO LOMI O!

Fun anfani awa ti a fe pe iya omo lati ki won a le pe won sori ero ibanisoro yi.

ODO
EJO
ODO
ETA
ARUN
ESAN
ETA
ESAN
ARUN
EJO
ODO

`Abel Simeon Oluwafemi‎

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo