Home / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro 02-04-2016

Iwure Owuro 02-04-2016

E MAA WI TELE MI :
…….
*Edumare ma je ki n soore daran.
*Oluwa ma je ki n gbalejo oran.
*Edumare ba mi segun elenini.
*Oluwa ran alaanu si mi.
*Edumare gba mi lowo alaroka.
*Oluwa dakun rojo ibukun sinu ise mi (Ase).
……….
‪#‎OLUWURE‬ : Abileko Yemi Owoyomi Oke.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo