Home / Àṣà Oòduà / Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti

Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti

Gomina Ayo fayose ti kede nomba ero ibanisoro re lori eto olosoosu kan to maa waye lori redio ati telifisan ipinle Ekiti, “E PADE GOMINA”.

Lori eto yii ni gomina ti n jiyin awon ise iriju re fun awon eniyan ipinle Ekiti nipa awon ohun meremere to ti gbese ati eyi to n se lowo.

Bakan naa lo tun fi kun un wi pe,” mi o ni ohunkohun lati fi pamo. Mo n jiyin ise iriju mi.

Nomba foonu mi ni yii, 08035024994. E pe mi. Ti mi o ba gbe, e fi atejise ranse. Maa ka, ma si fi esi ranse pada.

Eyin eniyan mi, e ma mikan. Olorun yoo se gbogbo ohun ta n fe. Mo gbagbo ninu Olorun, yoo si ran wa lowo lati bori”. – Fayose

Lojo isegun to koja yii, Gomina Fayose fun awon abarapa mewaa nise nigba to ko keke fun awon aro bi marunlelogbon (35).

Akowe iroyin fun gomina Fayose, Idowu Adelusi, so wi pe eyi wa lara eto lati fi sami odun kan gomina lori oye.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo