Tag: Àṣà Yorùbá

  • Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).

    Àwon àwòrán tí ó rewà tí Lota Chukwu fi se ayeye ojó ìbí rè nígbá tí ó pé omo odún mókàndínlógbòn (29).
    Gbajúgbajà arewà òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó n jé Lota Chukwu se ayeye odún mókàndínlógbon ojó ìbí rè ní àrà òtò, nígbà tí ó fi àwòrán tí ó dára jowá lójú, tí ó sì fi yàwá lénu púpò.
    Àwon àwòrán náa rewà púpò jù, e wò ní ìsàlè.

  • Arábìnrin omo odún méèdógbòn, tí ó tún jé a fi ewà s’oge, Chidimma Leilani Aaron ti gba àmì èye gégé bíi omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.

    ,Chidimma Leilani Aaron, omo odún méèdógbòn láti ìpínlè Enugu ti tayo àwon métàdínlógún (17) tí won jo díje fún omidan àkókó ní orílè èdè Nìjíríà ti odún yí. O di eni kejìlélógójì tí yóò gba àmì èye yí ó sì lo ilé pèlú mílìònù méta náírà.
    Ameh Rose ni ó se ipò keta tí Dunu sì se ipò kejì.
    Gégé bí iwé ìròyìn daily times se se agbáterù rè, àjòdún tí ó máa n wáyé ní odoodún yí wáyé ní ilé ìtura ní ìlú Eko tí a mò sí Eko hotel. Òpòlopò àwon gbajúgbajà ènìyàn ni ô sì lo fún ojú lóúnje níbè.
    Àwon Adájó ibè náà ni Rita Dominic, Ruchard Mofe Damijo, Olisa Adibua, Leesi Peter Vigbooro, Konye Nwabogor, Fade Ogbunro àti béè béè lo.
    Ebuka àti Kayla Oniwo ni ó sì se agbáterù rè.

  • Tobi Bakre ya àwòrán pèlú Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka.

    Ará ilé BBNaija télè tí ó sì jé àyànfé òpò ènìyàn tí a mò sí Tobi Bakre lo sì orí èro ayélujára rè tí ó n jé Insítágírámù láti pín àwòrán òhun àti àwon ènîyàn pàtàkì bíi Rita Dominic, Lolu, Bovi àti Ebuka ní ibi ìdíje eni tí yóò jé olómoge àkókó ní orílè èdè Nìjíríà tí odún 2018.
    E wo àwòrán òun pèlú Ebuka àti Bovi.

  • Goodluck Ebele Jonathan se ayeye odún mókànlélógóta (61) ojó ìbí rè ní èní.

    Goodluck Ebele Azikiwe Jonathan GCFR GCON tí won bí ní ogún’jó osù Belu ní odún 1957, tí ó jé olósèlú ní orílè èdè Nìjíríà tí ó sì sin ìlú gégé bíi Ààre orílè èdè Nìjíríà láti odún 2010-2015. Kí ó tó di wípé ó di Ààre ó ti kókó sìnlú gégé bíi Igbákejì Ààre orílè èdè yí ní odún 2007 di 2010 àti gégé bíi Gómìnà Ìpínlè Bayelsa láti odún 2005 di odún 2007.
    Ó pàdánù ìdíjé fún Ààre orílè èdè Nìjíríà ní odún 2015 tí Ààre Muhammad Buhari sì gbégbá orókè, òun ni Ààre àkókó tí ó wà lórì oyè tí ó sì tún pàdánù ìbò.

  • Kí ni ojú ò rírí, kárí ká f’ojú fò lópò. Njé Eléhà ninèyí tàbí Egúngún?.

    Òrò náà só síni lénu ó tún buyò si, àbí bí èèyàn yóò bá jé òsákálá kí ó jé Òsákálá bí yóò sì jé Òsokolo kí ó ké Òsokolo, èwo ni òsákálásokolo. Èyí èèyàn sé Eléhà ni a ó pe eléyìí ni àbí Egúngún?. Eléyìí kojá òyé ti èmi.
    Kí á ti è má fa òrò gún kò kúkú sí ìyàtò láàrin àwon méjèjì, èkú oko ni ìyàwó rè n wò kiri.

  • Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.

    Ògbóntarìgì Adigunjalè tí ó n dà àwon ará Delta láàmú ni owó ti tè.
    Ògbólògbó adigunjalè ní òrò won ti já sí òfo látàrí àì jé kí àwon èèyàn ní ìfòkànbalè ní ìpínlè Delta.
    Àwon adigunjalè méjì tí ó n da àwon ará ìlú Igbodo ti ìjoba ìbílè ti Gúúsú Ika àti agbègbè rè láàmú ní àwon olùdábòbò ìjoba ti pa.
    A gbó wípé àwon ìgárá Olósà pàdé ikú ní òwúrò ojó Etì (Friday) nígbà tí owó àwon olópàá àti figilanté bà wón.
    Àwon afurasí nígbà tí won fi èsùn kàn wón nígbà tí won n gbìyànjú àti ja okò nlá tí ó kó síméntì ló lè.
    A gbó wípé olórí àwon olósà yí tí a mò sí “CHOPPING” kí ó tó di wípé ó kú ni ó tí n da àwon arìn rìn àjò láàmú tí àwon ará ìlú kò sì le wo, nígbà tí ó n wo ilé lo jà wón lólè tí ó sì tún gba àwon ohun ìní won.
    Ìròyìn ikú rè àti ti àwon akegbé rè dún mó àwon ará ìlú nínú púpò jú, tí won sì kó àwon tí ó kù sí àgó olópàá.

  • Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.

    Babajide Sanwoolu àti Obafemi Hamzat pàdé àwon ìlúmòóká Òsèré.
    Omo egbé APC tí won yàn láti díje fún ipò Gómìnà ní ìpínlè Eko, tí a mò sí Babajide Sanwoolu àti akegbé rè tí òun a máa jé, Omòwé Obafemi Hamzat ní ìlú Èkó ní àná pàdé àwon gbajúgbajà àti àwon òsèré nlá nlá.
    Won sòrò nípa ètò orò ajé to ìpínlè Èkó ní ìgbà ti won.Àwon òsèré bíi Yinka Quadri, Adebayo Salami (Oga Bello), Jide Kosoko àti béè béè lo.

  • “Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.

    “Mo ti rí eni náà” Burna Boy pín àwòrán tí ó rewà pèlú arábìnrin arewà kan.


    Gbajúgbajà àti ogbóntarìgì olórin tí a mò sí Burna Boy nse ni ó dàbí eni wípé ó ti rí àyànfé, ó pín àwòrán tí won dì mó ara won, bí ó tilè jé wípé a kò mo arábìnrin arewà yí.
    Ó pín àwòrán náà pèlú òrò tí ó ya ni lénu.
    E wo àwòrán náà.

  • Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai .

    Cee C jáde pèlú Uriel àti Craze Clown ní Dubai .
    Àwon ará ilé BBnaija télè, Cee C àti Uriel ya àwòrán papò pélù Craze Crown ní orílè èdè Dubai.
    E wo àwòrán àwon àwom métèta tí ó rewà púpò jù.

  • Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.

    Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó olùwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tó jé Engineer.
    Olúwòsàn tí ó tún lóyún sínú àti oko rè tí ó jé Engineer ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Arábìnrin yí sì rewà púpò.
    Àwòrán náà wojú rí.