Olorun si maa gbesan iku baba mi – Omo ojo OloyunOjo ketalelogun osu kin-in-ni odun yii ni awon adiha-Moran kan lo yinbon pa Alhaji Fatai Yusuf ti gbogbo eniyan mo si oko oloyun. Lati igba naa ni awon olopaa ti ...
Read More »Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19
Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to ...
Read More »Ìjọba àpapọ̀: À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ, kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀
À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ ,kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀- Ìjọba àpapọ̀ Iléeṣẹ́ tó wà fún ìpèsè ohun ìrànwọ́ nílẹ̀ wa ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nínú àtẹjáde kan tó fisíta lójú òpó abẹ́yefò Twitter ...
Read More »Ewì Toni: Ìwà rere
*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí ...
Read More »Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC
Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò ...
Read More »Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru Lemon
Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru LemonBí a bá dájó̩, o̩jó̩, á pé, bí a dósù, osù á kò. Gbogbo o̩jó̩ ko̩kàndínló̩gbò̩n, osù ké̩rin o̩dún ni o̩jó̩ò̩bí Alhaji Sikiru Lemon. Yorùbá bò̩,wó̩n ní “àìbá wo̩n sí níbè̩ ni àìbá wo̩n dá síi”. Ìwé ...
Read More »Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ bẹ̀rẹ̀ fínfín ìtagbangba ní Ifẹ̀
Ọọ̀nirìṣà ilé Ifẹ, jìngbìnì bí àtẹ àkún,Ọba Adéyẹyè Ẹnitan Ogunwusi bẹ̀rẹ̀ fínfín àwọn ìta gbangba gbogbo ní ìlú Ilé Ifẹ̀ lẹ́yìn tó kéde ríra àwọn ohun èlò afínko láti dẹ́kun ọwọ́jà àrùn apinni léèmí COVID-19. Ọba Adéyẹyè ra àwọn irinṣẹ́ ...
Read More »Maryam Sanda ṣì wà lẹ́wọ̀n, Buhari kò dáa sílẹ̀.
Iléeṣẹ́ Ààrẹ ló sọ pé Ìròyìn tó ń jà rànyìnrànyìn kiri pé Ààrẹ Muhammadu Buhari tí darí jin arábìnrin náà kìí ṣe òtítọ́ rárá.Ki àwọn èèyàn kọtí ọ̀gbọin sí i.Ní oṣù kínní ọdún yìí ni ilé ẹjọ́ dá arábìnrin Maryam ...
Read More »Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo
Aiba won si nibe ni aiba won da sii. Eyi lo mu ki Alaga ile-iwe ati oludari, Mama Winfrey Awoshika ati Ibironke Adeyemi pese iresi, ewa, gaari ati ororo repete fun awon ti o ku die fun ni awujo.
Read More »Àdúrà làsìkò yí gbà pẹ̀lú ìfaradà láti ṣẹ́gun àrùn apinni léèmí Coronavirus–Ààrẹ Buhari
Ààrẹ Buhari kí àwọn ọmọ Nàìjíríà kú àfaradà bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ lásìkò Coronavirus yìí Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni kú ọdún Àjíǹde tó fi ṣọwọ́ sáwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ààrẹ Buhari ṣàlàyé pé ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kìí ...
Read More »