Home / Àṣà Oòduà / Osa Eleye!
osa eleye

Osa Eleye!

Ogbón kan mbe níkùn Asá,
Ìmòràn kan mbe níkùn Àwòdì,
Òkàn níkùn e, Òkàn níkùn mi,
Òkàn níkùn ara wa,
Diafun Òrúnmìlà,
Baba ñ loree b’awon Àjé mulè nígbó Olúkórómójó,
Wón ní kílódé,
O ní nitori kí Ayé le gun
O ní nitori kí igba le rò

About asatiwa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Mosalasi Fe Di Wiwo Fun ile Adire