Home / Àṣà Oòduà / Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.

Ejò nlá kan (paramólè) tí won pa ní agbègbè mi láìpé ní àró yí.

Ní àárò yí nígbà tí mo ti setán láti ma lo sí ibi isé ni mo pàdé àwon ògbéni yí, tí won n yo látàrí wípé won pa ejò, tí mo rò wípé paramólè ni, tí won sì ti gbèrò láti sè je .

Ó ti è ti pé tí mo ti fi ojú mi kòrókòró kan ejò nlá. Èrù bàmí ó sì yà mí lénu nígbà tí arákùnrin yí fi kó orùn, tí kò sì bèrù .
E gbó sé èyin le je irú ejò báyìí?emi kò le je o .

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?