Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára.
A gbó wípé kò sí ibi náà tí e ó ti ri Aláàfin tí e kò ni ri Olorì Ola níbè.
Olorì ti se ayeye ojo ìbí rè ní àrà òtò látàrí pínpín àwòrán tó yááyì.
Comments
One response to “Olorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí ó wuyì.”
[…] from Ọmọ Oòduà http://ooduarere.com/news-from-nigeria/breaking-news/olo-bas-ti/ […]