E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?

Written by

in

Leyin ti won fi Sanusi je Emir tilu Kano, oba. Ilu Kano si gba wi pe oosa ajiki bi iya ko si laye. Eleyii lo mu gomina banki agba ile yii nigba kan ri teriba niwaju yeye to bi i lomo.

Nje asa Yoruba tewogba iru ohun ti Sanusi se yii?
Nje Ooni tuntun le se iru re?
Ninu iya eni ati ipo oba, e wo lo gaju?

Comments

One response to “E ba wa dasi oro yii: Ninu ipo ati iya eni, e wo lo gaju?”

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *