Home / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko

E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko


Gomina Ambode ti ilu eko ti ko opolopo ohun elo bi moto, oko ojuomi, oko ofurufu ati okada fun awon agbofinro ipinle naa lati le gbogun ti iwa idaran ni ipinle naa. Minisita fun eto abenu, Rahman Dambazzau lo soju Aare Buhari nibi ayeye naa.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?