Home / Àṣà Oòduà / Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin tè s’ílé nítorí wípé kò ní isé l’ówó bá pátá àti róbà ìdábòbò nínú ilé rè.

Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin tè s’ílé nítorí wípé kò ní isé l’ówó bá pátá àti róbà ìdábòbò nínú ilé rè.

     Gégé bí ìtàn se so è yun-ùn tí won pín sí orí èro ayélujára (IG) ti Joro Olumofin. Òdómobìnrin tí ó gba òrékùnrin rè tí kò n’ísé l’ówó gbé nínú ilé rè ní Eko padà délé láti ìrìn-àjò tí ó lo láti ya òrékùnrin rè lénu sùgbón tí ó padà ri wípé n se ni omokùnrin náà n re je.

Gégé bí ó se so, òrékùnrin náà n fi tipátipà jé kí ó fi pátá tí ó won ìwòn mérìnlá (14) sílè fún oní ìwòn méwàá(10) sùgnón ìyàlénu lójé wípé obìnrin náà rí pátá tí ó won ìwòn méjìdínlógún nínú balùwè…

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Aáyẹ tí ó de bá àṣà

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àṣà máa ń yí padà nípa aṣo wíwọ̀, ìgbéyàwó, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ, lóde-òní, ètò ẹ̀kọ́ àti ìwà ọ̀làjú tó gbòde kan ti ṣe àkóbá fún àṣà ní àwọn ọ̀nà wọ̀nyí: (a) Ìwọsọ wa kò bójú mu mọ́. (b) Àṣà ìkíni wa kò ní ọ̀wọ̀ nínú mọ́. (d) Kí’yàwó ilé má mọ oúnjẹ ìbílẹ̀ ṣè mọ́. (e) A kò mọ ìtumọ̀ àrokò tí a ń kọ́ àwọn ọmọ wa mọ́. (ẹ) A kò fi èdè ...