Afárá (Bridge ) yí ni òjò ti gbá dànù láti bí osù díè séyìn látàrí òjò nlá tí ó rò tí àwon ìjoba kò sì se nkankan si . ònà alágbàdo ni afárá yí wà . Nígbà tí mo dé Ilorin òná yí ni ó ye kí n gbà sugbòn tí mo padà lo gba ònà tí ó jì jù lo…

Tagged with: Àṣà Yorùbá