Home / Àṣà Oòduà / Alágemo tó se jéjé ikú pa á.

Alágemo tó se jéjé ikú pa á.

Kí á dijú ká se bí eni tí ó kú kí á wo eni tí yó se ìdárò eni
Ká fi esè ko gbàù kí á wo eni tí yó seni pèlé
Ayé laó ti mo eni tí ó ń fé teni
Ayé La Ó ti mo èèyàn àtàtà
Nítorí ojú larí kòdénú
Ìbá jé wípé inú se sín bí igbá ni à bá kúkú mo èèyàn àtàtà
Àfi kí á se rere
Kí á tún te ilè jéjé
Nítorí Alágemo tí ó se jéjé ikú paá ábàlètànsé òpòlò tí ó gbé ara è sánlè
Ará mi ayé le.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo