Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare.
Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú Ekan Egonmwa. Ó sì ti se ayeye láti yo esè kúrò láwùjo olómoge ní ìparí òsè tí ó lo.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?