Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren .

Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren . Banky W àti òré rè tímótímó fún ìgbéyàwó alárédè rè, Tunde Demuren ni won Jo ya àwòrán papò níbi ìgbéyàwó alárinrin ni won sì se jómírégí papò.

Èyí wù mí.

Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *