Home / Àṣà Oòduà / Davido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.

Davido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.

Davido àti òrébìnrin rè, Chioma wà ní Barbados báyìí báyìí láti ya àwòrán Orin tuntun tí Davido sèsè ko.
Ó ti pín àwòrán òun àti arábìnrin yí ní orí èro ayélujára tí a mò sí instagram tí ó sì ko síbè pé àsedúró ayérayé.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*