Home / Àṣà Oòduà / E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

   Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára bí eni máa kú, kí won bò wá lówó àti kí á fi àkókò sòfò láti múra láti fi dàbí egbin, kí a sì gba èbùn gbàngba ! Sí ò .

Eni tí ó gba òdómobìnrin arewà jùlo àti òdómokùnrin arewà jùlo ti ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èko ní odún 2014 gba okò bògìnì tí eni tí ó sì mo ìwé jù gba èbún laptop.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo