Home / Àṣà Oòduà / Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo

Eniyan koni rajo kofi orire kale sile ibiti aba koriwa mase pada leyinwa oo

Ori mi Apere
isedami Ajifobi kan
Amuni wale aye magbagbe Eni
Orimi gbemi bose gbe omo alara tofidade owo
isedami gbemi bosegbe omo ajero tofi tepaleke
orimi gbemi bose gbe
omo orangun ila tofidi eni apesin pitipiti
mogbani Adurafun wape
oriwa Asegbe funwa o
ifa ni
sakasala legbe leke
Adifafun ori omo Amuwa gun boroboro
ebo lawoni komuse osi gbebobe orubo
eropo eroofa eyin omon
pe orilamuwa gun awo.

bi ori eni basunwan
wan ani ori enida
isedami jeki orimisunwan korimidi ori ola ati olaa ki mase se eru egbe mi oo
# Babalawo Ifatola Sangodare Awosipe

Eniyan koni rajo kofi orire kale_ooduarere.com_

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo