Home / Àṣà Oòduà / Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

   Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti férè se tán láti sín.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?