Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé.
Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí kò se wípé ó tún fún won àwon èbún míràn.

About Awo

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?